Connect with us

Lyrics

LYRICS: King Ashemalu – Odomi

Published

on

Intro

Cho!
Adibo!
Skelenbe!
Hololo…………uh.
King Ashemalu
Small Body Big Engine
Ashe.

Verse 1

Aya toba farabalè
Oma jere ôkô
Iroko ninun ésodi orikejila gan lontiso
Gboro soko lénu
Ma gbolénu ma solénu
Ori bédi ni kofija yen si ko folénu
Kiss your boo
Oni soribuu
Awon omo tonbé nita wongbadun 2x
Won ma bébojé.

Chorus

OdoMi wagunmi
Wagunmi OdoMi 2x
OdoMi wagunmi o
Wagunmi OdoMiii

Hook
Idi orémi lemi ofisi ihihiii
Idi orémi talantolo o 2x.

Verse 2

Okunrin tofara balé loma jere Aya
Obinrin kiki’da mistake
Alawoku niwan dimeji
Oma sebi ôkô
Oma sebi Baba
Oma sebi Broda
Igbakugba lonigba.
Gboro soko lénu ma gbolénu ma solénu
Ori bédi ni kofija yensi kofolénu
Kiss your boo
Oni soribuu
Awon omo tonbé nita wongbadun
Wongbadun, Won ma bébojé.

Chorus

OdoMi wagunmi
Wagunmi OdoMi 2x
OdoMi wagunmi o
Wagunmi OdoMiii

H00k
Idi orémi lemi ofisi ihihiii
Idi orémi talantolo o 2x.

DOWNLOAD HERE

Click to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

OUR SERVICE

Recent Post




ADS

Trending